Nipa Iwe Naa Nje otito ni wipe aye yoo wa s’opin lojo kan? Bawo ni yoo se sele? Ki o to sele, kini eto ti Olorun ni fun awon ayanfe Re ati pe kini o gbodo je imura sile awa Omo Olorun? About the Book Is it true that the world will come to an end one day? How will it happen? Before it happens, what plan does God have for His beloved ones, and what kind of preparation should we, the children of God, make?