Ose Lydia Auxiliary - [Elijah Baptist Church Adjame] - Alufa & Ajihinrere Tokunbo Francis JP

Ose Lydia Auxiliary - [Elijah Baptist Church Adjame] - Alufa & Ajihinrere Tokunbo Francis JP

Ose-Lydia Auxiliary Ninu Isin Ojo Isinmi. Date: 26th July, 2020 Ninu Ijo Elijah Baptist Church Adjame Ori-Oro: IBANIWI ONA SI ASEYORI Ese-Bibeli: OWE 3:11-12; 12: 1 Oniwaasu: Rev. Tokunbo Francis (JP) Gbogbo awọn eto ọlọsọọsẹ wa: Gbogbo wednesday ipade adura lati 6.30 p.m. si 8 p.m.(Elijah Baptist Church Adjame) Gbogbo thursdays eto alabarin lati 7 p.m. si 8 p.m.(Facebook:Eri Ipe) Gbogbo ọjọ friday iso-oru lati 00 a.m si 02 a.m (Facebook: Elijah Baptist Church Adjame ) Gbogbo sundays Isin Owuro Ojo Isinmi lati ago 7 a.m si 10 a.m (Facebook: Elijah Baptist Church Adjame ). Esi le kan si wa lori awon ero ibanisoro wa wonyin: Facebook: Elijah Baptist Church Adjame E-mail: [email protected] Youtube: Elijah Baptist Church Tv Rev'd & Evang Tokunbo Francis JP. What's App Number: Civ: +225 46 38 27 27 +225 02 02 77 28 Nig: +234 80 69 35 54 40 Phone line: (+225) 21 79 29 46 Mobile Phone: (+225 46 38 27 27). Di Alabunkufun ni oruko JESU KRISTI Amin.